Kronika Keji 34:7 BM

7 Ó wó àwọn pẹpẹ, ó lọ àwọn òpó Aṣera ati àwọn ère oriṣa lúúlúú, ó sì wó gbogbo pẹpẹ turari jákèjádò ilẹ̀ Israẹli. Lẹ́yìn náà ó pada sí Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Kronika Keji 34

Wo Kronika Keji 34:7 ni o tọ