Deu 10:13 YCE

13 Lati ma pa ofin OLUWA mọ́, ati ìlana rẹ̀, ti mo filelẹ fun ọ li aṣẹ li oni, fun ire rẹ?

Ka pipe ipin Deu 10

Wo Deu 10:13 ni o tọ