Deu 10:15 YCE

15 Kìki OLUWA ni inudidùn si awọn baba rẹ lati fẹ́ wọn, on si yàn irú-ọmọ wọn lẹhin wọn, ani ẹnyin jù gbogbo enia lọ, bi o ti ri li oni yi.

Ka pipe ipin Deu 10

Wo Deu 10:15 ni o tọ