Deu 10:5 YCE

5 Mo si pada, mo si sọkalẹ lati ori òke na wá, mo si fi walã wọnni sinu apoti ti mo ti ṣe; nwọn si wà nibẹ̀, bi OLUWA ti paṣẹ fun mi.

Ka pipe ipin Deu 10

Wo Deu 10:5 ni o tọ