Deu 12:2 YCE

2 Ki ẹnyin ki o run ibi gbogbo wọnni patapata, nibiti awọn orilẹ-ède nì, ti ẹnyin o gbà, nsìn oriṣa wọn, lori òke giga, ati lori òke kekeké, ati labẹ igi tutù gbogbo:

Ka pipe ipin Deu 12

Wo Deu 12:2 ni o tọ