Deu 13:11 YCE

11 Gbogbo Israeli yio si gbọ́, nwọn o si bẹ̀ru, nwọn ki o si tun hù ìwabuburu bi irú eyi mọ́ lãrin nyin.

Ka pipe ipin Deu 13

Wo Deu 13:11 ni o tọ