Deu 18:12 YCE

12 Nitoripe gbogbo awọn ti nṣe nkan wọnyi irira ni si OLUWA: ati nitori irira wọnyi ni OLUWA Ọlọrun rẹ ṣe lé wọn jade kuro niwaju rẹ.

Ka pipe ipin Deu 18

Wo Deu 18:12 ni o tọ