Deu 18:18 YCE

18 Emi o gbé wolĩ kan dide fun wọn lãrin awọn arakunrin wọn, bi iwọ; emi o si fi ọ̀rọ mi si i li ẹnu, on o si sọ fun wọn gbogbo eyiti mo palaṣẹ.

Ka pipe ipin Deu 18

Wo Deu 18:18 ni o tọ