Deu 22:7 YCE

7 Bikoṣe ki iwọ ki o jọwọ iya lọwọ lọ, ki iwọ ki o si kó ọmọ fun ara rẹ; ki o le dara fun ọ, ati ki iwọ ki o le mu ọjọ́ rẹ pẹ.

Ka pipe ipin Deu 22

Wo Deu 22:7 ni o tọ