Deu 23:9 YCE

9 Nigbati iwọ ba jade ogun si awọn ọtá rẹ, nigbana ni ki iwọ ki o pa ara rẹ mọ́ kuro ninu ohun buburu gbogbo.

Ka pipe ipin Deu 23

Wo Deu 23:9 ni o tọ