Deu 25:2 YCE

2 Yio si ṣe, bi ẹlẹbi na ba yẹ lati nà, ki onidajọ na ki o da a dọbalẹ, ki o si mu ki a nà a ni iye kan li oju on, gẹgẹ bi ìwabuburu rẹ̀.

Ka pipe ipin Deu 25

Wo Deu 25:2 ni o tọ