Deu 28:14 YCE

14 Iwọ kò si gbọdọ yà kuro ninu gbogbo ọ̀rọ ti mo palaṣẹ fun nyin li oni, si ọtún, tabi si òsi, lati tọ̀ ọlọrun miran lẹhin lati sìn wọn.

Ka pipe ipin Deu 28

Wo Deu 28:14 ni o tọ