37 Iwọ o si di ẹni iyanu, ati ẹni owe, ati ẹni ifisọrọsọ, ninu gbogbo orilẹ-ède, nibiti OLUWA yio gbé darí rẹ si.
Ka pipe ipin Deu 28
Wo Deu 28:37 ni o tọ