Deu 28:59 YCE

59 Njẹ OLUWA yio sọ iyọnu rẹ di iyanu, ati iyọnu irú-ọmọ rẹ, ani iyọnu nla, ati eyiti yio pẹ, ati àrun buburu, ati eyiti yio pẹ.

Ka pipe ipin Deu 28

Wo Deu 28:59 ni o tọ