Deu 29:7 YCE

7 Nigbati ẹnyin ti dé ihinyi, Sihoni ọba Hesboni, ati Ogu ọba Baṣani, jade ogun si wa, awa si kọlù wọn:

Ka pipe ipin Deu 29

Wo Deu 29:7 ni o tọ