Deu 29:9 YCE

9 Nitorina, ẹ pa ọ̀rọ majẹmu yi mọ́, ki ẹ si ma ṣe wọn, ki ẹnyin ki o le ma ri ire ninu ohun gbogbo ti ẹnyin nṣe.

Ka pipe ipin Deu 29

Wo Deu 29:9 ni o tọ