Deu 30:17 YCE

17 Ṣugbọn bi àiya rẹ ba pada, ti iwọ kò ba si gbọ́, ṣugbọn ti iwọ di ẹni fifà lọ, ti iwọ si mbọ oriṣa, ti iwọ si nsìn wọn;

Ka pipe ipin Deu 30

Wo Deu 30:17 ni o tọ