Deu 32:22 YCE

22 Nitoripe iná kan ràn ninu ibinu mi, yio si jó dé ipò-okú ni isalẹ, yio si run aiye pẹlu asunkún rẹ̀, yio si tinabọ ipilẹ awọn okenla.

Ka pipe ipin Deu 32

Wo Deu 32:22 ni o tọ