Deu 4:20 YCE

20 Ṣugbọn OLUWA ti gbà nyin, o si mú nyin lati ileru irin, lati Egipti jade wá, lati ma jẹ́ enia iní fun u, bi ẹnyin ti ri li oni yi.

Ka pipe ipin Deu 4

Wo Deu 4:20 ni o tọ