Deu 4:28 YCE

28 Nibẹ̀ li ẹnyin o si ma sìn oriṣa, iṣẹ ọwọ́ enia, igi ati okuta, ti kò riran, ti kò si gbọran, ti kò jẹun, ti kò si gbõrun.

Ka pipe ipin Deu 4

Wo Deu 4:28 ni o tọ