Deu 6:20 YCE

20 Nigbati ọmọ rẹ ba bi ọ lère lẹhin-ọla, wipe, Kini èredi ẹrí, ati ìlana, ati idajọ wọnyi, ti OLUWA Ọlọrun filelẹ li aṣẹ fun nyin?

Ka pipe ipin Deu 6

Wo Deu 6:20 ni o tọ