Deu 9:17 YCE

17 Emi si mú walã meji nì, mo si sọ wọn silẹ kuro li ọwọ́ mi mejeji, mo si fọ́ wọn niwaju nyin.

Ka pipe ipin Deu 9

Wo Deu 9:17 ni o tọ