Mátíù 12:27 BMY

27 Àti pé, bi èmi bá ń lé àwọn ẹ̀mí ẹ̀ṣù jáde nípa Béélísébúbù, nípa ta ni àwọn ènìyàn yín fi ń lé wọn jáde? Nítorí náà ni wọn yóò ṣe má ṣe ìdájọ́ yín.

Ka pipe ipin Mátíù 12

Wo Mátíù 12:27 ni o tọ