Mátíù 12:28 BMY

28 Ṣùgbọ́n bí ó bá jẹ́ pé nípa ẹ̀mí Ọlọ́run ni èmi fi ń lé àwọn ẹ̀mí ẹ̀ṣù jáde, a jẹ́ pé ìjọba Ọlọ́run ti dé bá yín.

Ka pipe ipin Mátíù 12

Wo Mátíù 12:28 ni o tọ