55 Kì í há ṣe ọmọ gbẹ́nàgbẹ́nà ni èyí bí? Ìyá rẹ̀ há kọ́ ni à ń pè ní Màríà bí? Arákùnrin rẹ̀ ha kọ́ ni Jémísì, Jósẹ́fù, Símonì àti Júdásì bí?
Ka pipe ipin Mátíù 13
Wo Mátíù 13:55 ni o tọ