Mátíù 13:56 BMY

56 Àwọn arábìnrin rẹ̀ gbogbo ha kọ́ ni ó ń bá wa gbé níhìn-ín yìí, nígbà náà níbo ni ọkùnrin yìí ti rí àwọn nǹkan wọ̀nyí?”

Ka pipe ipin Mátíù 13

Wo Mátíù 13:56 ni o tọ