Mátíù 14:29 BMY

29 Jésù dá a lóhùn pé, “Ó dára, máa bọ̀ wá.”Nígbà náà ni Pétérù sọ̀ kalẹ̀ láti inú ọkọ̀. Ó ń rìn lórí omi lọ sí ìhà ọ̀dọ̀ Jésù.

Ka pipe ipin Mátíù 14

Wo Mátíù 14:29 ni o tọ