Mátíù 14:30 BMY

30 Nígbà tí ó rí afẹ́fẹ́ líle, ẹ̀rù bà á, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í rì. Ó kígbe lóhùn rara pé, “Gbà mí, Olúwa.”

Ka pipe ipin Mátíù 14

Wo Mátíù 14:30 ni o tọ