Mátíù 14:5 BMY

5 Hẹ́rọ́dù fẹ pa Jòhánù, ṣùgbọ́n ó bẹ̀rù àwọn ènìyàn nítorí gbogbo ènìyàn gbàgbọ́ pé wòlíì ni.

Ka pipe ipin Mátíù 14

Wo Mátíù 14:5 ni o tọ