Mátíù 14:6 BMY

6 Ní ọjọ́ àsè ìrántí ọjọ́ ìbí Hẹ́rọ́dù, ọmọ Hẹ́rọ́díà obìnrin jó dáadáa, ó sì tẹ́ Hẹ́rọ́dù lọ́run gidigidi.

Ka pipe ipin Mátíù 14

Wo Mátíù 14:6 ni o tọ