Mátíù 16:13 BMY

13 Nígbà tí Jésù sì dé Kesaríà-Fílípì, ó bi àwọn ọmọ ẹ̀yin rẹ̀ pé, “Ta ni àwọn ènìyàn ń fi Ọmọ ènìyàn pè?”

Ka pipe ipin Mátíù 16

Wo Mátíù 16:13 ni o tọ