Mátíù 16:14 BMY

14 Wọ́n dá a lóhùn pé, “Àwọn kan ni Jòhánù onítẹ̀bọ́mì ni, àwọn mìíràn wí pé, Èlíjà ni, àwọn mìíràn wí pé, Jeremáyà ni, tàbí ọ̀kan nínú àwọn wòlíì.”

Ka pipe ipin Mátíù 16

Wo Mátíù 16:14 ni o tọ