23 Jésù pa ojú dà, ó sì wí fún Pétérú pé, “Kúrò lẹ́yìn mi, Sàtáni! Ohun ìkọ̀ṣẹ̀ ni ìwọ jẹ́ fún mi; ìwọ kò ro ohun tí i se ti Ọlọ́run, bí kò se èyí ti se ti ènìyàn.”
Ka pipe ipin Mátíù 16
Wo Mátíù 16:23 ni o tọ