Mátíù 16:22 BMY

22 Pétérù mú Jésù sí ẹ̀gbẹ́ kan, ó bẹ̀rẹ̀ sí í bá a wí pé, “Kí a má rí i Olúwa. Èyí kì yóò ṣẹlẹ̀ sí Ọ.”

Ka pipe ipin Mátíù 16

Wo Mátíù 16:22 ni o tọ