Mátíù 16:27 BMY

27 Nítorí Ọmọ ènìyàn yóò wá nínú ogo baba rẹ pẹ̀lú àwọn ańgẹ́lì rẹ̀, nígbà náà ni yóò sì san án fún olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 16

Wo Mátíù 16:27 ni o tọ