Mátíù 17:24 BMY

24 Nígbà tí Jésù àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì dé Kápánámù, àwọn agbowó-òde tọ Pétérù wá wọ́n sì bí i pé, “Ǹjẹ́ Olúwa yín ń dá owó tẹ̀ḿpìlì?”

Ka pipe ipin Mátíù 17

Wo Mátíù 17:24 ni o tọ