Mátíù 17:25 BMY

25 Pétérù sì dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, ó ń san.”Nígbà tí Pétérù wọ ilé láti bá Jésù sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀, Jésù ni ó kọ́kọ́ sọ̀rọ̀, Jésù bí i pé, “Kí ni ìwọ rò, Símónì? Ǹjẹ́ àwọn ọba ń gba owó-orí lọ́wọ́ àwọn ọmọ wọn tàbí lọ́wọ́ àwọn àlejò?”

Ka pipe ipin Mátíù 17

Wo Mátíù 17:25 ni o tọ