Mátíù 18:26 BMY

26 “Nígbà náà ni ọmọ-ọ̀dọ̀ náà wólẹ̀ lórí eékún níwájú rẹ. ‘Ó bẹ̀bẹ̀ pé, mú sùúrù fún mi, èmi yóò sì san gbogbo rẹ̀ fún ọ.’

Ka pipe ipin Mátíù 18

Wo Mátíù 18:26 ni o tọ