Mátíù 18:4 BMY

4 Nítorí náà, ẹni tí ó bá rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọmọdé yìí, ni yóò pọ̀ jùlọ ní ìjọba ọ̀run.

Ka pipe ipin Mátíù 18

Wo Mátíù 18:4 ni o tọ