Mátíù 19:26 BMY

26 Jésù sì tẹjú mọ́ wọn, ó wí pé, “Bí o bá jẹ́ ti ènìyàn ni, eléyìí sòro. Ṣùgbọ́n bí ó bá ṣe ti Ọlọ́run ni, ohun gbogbo ni ṣíṣe.”

Ka pipe ipin Mátíù 19

Wo Mátíù 19:26 ni o tọ