Mátíù 19:27 BMY

27 Pétérù sì wí fún un pé, “Àwa ti fi ohun gbogbo sílẹ̀, a sì tẹ̀lé Ọ. Kí ni yóò jẹ́ èrè wa?”

Ka pipe ipin Mátíù 19

Wo Mátíù 19:27 ni o tọ