Mátíù 20:19 BMY

19 Wọn yóò sì lé àwọn kèfèrí lọ́wọ́ láti fi ṣe ẹlẹ́yà àti láti nàa án, àti láti kàn mi mọ́ àgbélébùú, ní ọjọ́ kẹta, yóò jí dìde.”

Ka pipe ipin Mátíù 20

Wo Mátíù 20:19 ni o tọ