Mátíù 21:34 BMY

34 Nígbà ti àkókò ìkórè súnmọ́, ó rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sí àwọn àgbẹ̀ náà láti gba èyí ti ó jẹ tirẹ̀ wá.

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:34 ni o tọ