Mátíù 22:21 BMY

21 Wọ́n sì dáhùn pé, “Ti Késárì ni.”“Nígbà náà ni ó wí fún wọn pé,” “Ẹ fi èyí tí í ṣe ti Késárì fún Késárì, ẹ sì fi èyí ti ṣe ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”

Ka pipe ipin Mátíù 22

Wo Mátíù 22:21 ni o tọ