Mátíù 22:22 BMY

22 Nígbà tí wọ́n gbọ́ èyí, ẹnú yà wọ́n. Wọ́n fi í sílẹ̀, wọ́n sì bá tiwọn lọ.

Ka pipe ipin Mátíù 22

Wo Mátíù 22:22 ni o tọ