Mátíù 24:43 BMY

43 Ṣùgbọ́n, kí ẹ mọ èyí pé, baálé ilé ìbá mọ wákàtí náà tí olè yóò wá, ìbá máa ṣọ́nà, òun kì bá ti jẹ́ kí a já wọ ilé rẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 24

Wo Mátíù 24:43 ni o tọ