Mátíù 24:44 BMY

44 Nítorí náà, ẹ gbọdọ̀ wà ní ìmúra-sílẹ̀, nítorí ní wákàtí àìròtẹ́lẹ̀ ni dídé Ọmọ-Eènìyàn yóò jẹ́.

Ka pipe ipin Mátíù 24

Wo Mátíù 24:44 ni o tọ