Mátíù 26:14 BMY

14 Nígbà náà ni ọ̀kan nínú àwọn àpósítélì méjìlá ti à ń pè ní Júdásì Ìskáríọ́tù lọ sọ́dọ̀ àwọn olórí àlùfáà.

Ka pipe ipin Mátíù 26

Wo Mátíù 26:14 ni o tọ