Mátíù 26:15 BMY

15 Òun sì béèrè pé, “Kí ni ẹ̀yin yóò san fún mi bí mo bá fi Jésù lé yín lọ́wọ́?” Wọ́n sì fún un ní ọgbọ́n owó fàdákà. Ó sì gbà á.

Ka pipe ipin Mátíù 26

Wo Mátíù 26:15 ni o tọ