75 Nígbà náà ni Pétérù rántí nǹkan tí Jésù ti sọ pé, “Kí àkùkọ tóó kọ, ìwọ yóò sẹ́ mi nígbà mẹ́ta.” Òun sì bọ́ sí òde, ó sọkún kíkorò.
Ka pipe ipin Mátíù 26
Wo Mátíù 26:75 ni o tọ